'Èyí wù mí, kò wú ọ́, ni kìí jẹ́ kí ọmọ bàbá méjì fẹ́yàwó kan'

'Èyí wù mí, kò wú ọ́, ni kìí jẹ́ kí ọmọ bàbá méjì fẹ́yàwó kan'

'Ọyàn àwọn míràn tóbi ṣùgbọ́n kò wúwo bíi tèmi yii'

Obinrin kan ti BBC fọrọwalẹnuwò lóri títóbi ọyàn àyà rẹ ṣalaye pe ọyàn òun ti fẹ fún òun lọ́rùn pa ri nigba ti òun ń sùn lọjọ kan.

O ni òun kii ra bèrèkọ́yàn lọja nitori ọpọ ìgbà ni kìí sí sáìsì òun lọja ni ẹ̀gbẹ́ tabi ni ara.

Bẹẹ oúnjẹ ibikan jẹ èèwọ̀ ilẹ ibomiran ni ọrọ ile ayé.

'Bi àwọn kan ṣe máa ń ni àwọn fẹran ọmu mi tó níńlá ni àwọn miran maa ń fi bu mi'.

O ménuba irora ọyan rẹ yii nigba to wa nínu òyun pe bẹ́ẹ̀ ko yọ omi daadaa lẹyin ti òun bimọ tan àti pe ti òun ba ti ri owó ni òun yoo lọ ṣiṣẹ abẹ din ọyan ńla naa kù.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: