Real madrid vs Liverpool: Kiev ni aṣekagba idije Champions league yoo ti waye

Real madrid vs Liverpool: Kiev ni aṣekagba idije Champions league yoo ti waye

Wo bi gbagede papa iṣire Kiev, ti ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba idije Champions league yoo ti waye lọjọ Abamẹta.

Papa iṣire nla Kiev lorilẹede Ukrain lawọn ololufẹ Real Madrid, Liverpool ati gbogbo awọn ololufẹ ere bọọlu lagbaye ti n peju si bayi lati mọ ẹni ti yoo gba ade bọọlu afẹsẹgba laarin awọn ẹgbẹ agbabọọlu ilẹ Yuroopu lalẹ abamẹta.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: