Real Madrid vs Liverpool: Salah parí ìrìnàjò Champions league

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Salah, gbajúgbajà agbábọ́ọ̀lù Liverpool jáde nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ náà lẹ́yìn tó fi èjìká rẹ̀ ṣèṣe
Mohammed Salah ti jade kuro ninu papa iṣire ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba laarin Real madrid ati Liverpool.
Salah to jẹ ogunna gbongbo agbabọọlu Liverpool jade kuro lori papa lẹyin ti o ti fi apa rẹ ṣeṣe ninu ifẹsẹwọnsẹ naa.
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Mohammed Salah ti jade kuro ninu papa iṣire ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba laarin Real madrid ati Liverpool
Salah jẹ ọkan lara awọn irawọ agbabọọlu ti awọn eeyan n woye pe yoo tan bi oorun ninu ifẹsẹwọnsẹ naa.
Ọgbọn iṣẹju ni ifẹsẹwọnsẹ naa de nigba ti o jade.
Ẹkunrẹrẹ iroyin laipẹ