Ibrahim Chatta: Tí olólùfẹ́ méjì bá ti ń na ara wọn, ọ̀kan má a pa èkejì!

Ibrahim Chatta: Tí olólùfẹ́ méjì bá ti ń na ara wọn, ọ̀kan má a pa èkejì!

Gbajugbaja osere tiata Yoruba, Ibahim Chatta ti ni ololufẹ meji to ba ti fẹran ara wọn gbọdọ ni igbagbọ ninu ara wọn.

Chatta sọ eyi lasiko to n ba BBC Yoruba sọ̀rọ lori ẹsun wi pe o ma n na iyawo rẹ.

Ninu fidio yii, gbajugbaja osere naa salaye ipo ti igbeyawo rẹ̀ wà ati igbẹsẹ ti o gbe lati koju awọn ipenija ti o koju.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: