Kí ló wà nínú Tea tí Abiola mu?

Èsì ìwádìí àwọn Dókítà nípa ikú tó pá a fihàn pé kìí se àmúwá Ọlọ́run. Ọjọ́ keje osù keje ọdún 1998 ni Moshood Kashimawo Abiola jáde láyé.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: