World Cup 2018: Nàíjiríà kọ̀ le e gbé adiye wọ Russia

Adiyẹ Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Àwọn ololúfẹ́ Nàíjiríà kọ̀ le e gbé adiye wọ Russia

Awọn ololufẹ bọọlu ilẹ Naijiria beere fun aaye lati gbe adiyẹ laaye wọ ori papa isẹrẹ ni Russia lasiko ifẹsẹwọnsẹ laarin Naijiria ati Croatia.

Minisita fun ọrọ aṣa ati iṣe ni orilẹ-ede Russia, Andrei Ermak, lo sọ bẹẹ fun awọn akọrọyin lasiko igbaradi fun Ife Ẹyẹ Agbaye 2018.

Ermak sọ pe awọn ko le e fun awọn ololufẹ bọọlu lati orilẹ-ede Naijiria laaye lati gbe adiye wo ori papa ni gbogbo igba ti Naijiria ba ti n gba bọọlu lori paapa.

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ikọ̀ Super Eagles ti Nàìjíríà yóò fẹsẹ̀wọnsẹ̀ pẹ̀lú Croatia lọ́jọ̀ Sátidé níbi Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé ti Russia 2018 tó ń lọ lọ́wọ́

Minisita naa fikun wi pe papa isere ti Naijiria ti fẹ gba ni Ọjọ Satide pẹlu Croatia ni Kaliningrad ti yoo gba ọpọlọpọ eniyan lasiko naa.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption'Mi ò ní wo bọ́ọ̀lù mọ́ ti Nàìjíríà bá fìdírẹmi ni Russia 2018'

Ikọ̀ Super Eagles ti Nàìjíríà yóò fẹsẹ̀wọnsẹ̀ pẹ̀lú Croatia lọ́jọ̀ Sátidé níbi Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé ti Russia 2018 tó ń lọ lọ́wọ́

Nigba ti Egypt ati Uruguay yoo waa ko lọsan oni.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption'IBB da Abiola lẹ́yìn tó búra pẹ̀lú Quran'