World Cup 2018: Ijàkàdì kọ́, Ipele àkọ́kọ́ nínú ìdíje pari!

awon agbaboolu Colombia ati refiiri Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Rẹfiiri Milorad Mazic fun Johan Mojica Colombia ni kaadi Yelo

Èsì ìdíje ti gba omi ẹkún lójú ọpọlọpọ agbábọ́ọ̀lù atawọn olólùfẹ́ wọn ni Russia 2018.

Àrà ọ̀tọ̀ ni ìdíje eré bọ́ọ̀lù FIFA 2018 ń jásí lọ́tẹ̀ yìí.

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Senegal naa ja ninu idije Russia 2018

Àwọn ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù kọọkan ń ṣe ju bí àwọn èrò ṣe rò lọ nigba ti àwọn miiran n já wálẹ̀ láìròtẹ́lẹ̀. Ìdíje bọọlu ti gba iṣiro lọ́tẹ̀ yìí.

ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKINI RUSSIA VS SAUDI 5-0 14-06-2018
IKINI EGYPT VS URUGUAY 0-1 15-06-2018
IKEJI MOROCCO VS IRAN 0-1 15-06-2018
IKEJI PORTUGAL VS SPAIN 3-3 15-06-2018
IKẸTA FRANCE VS AUSTRALIA 2-1 16-06-2018
IKẸTA PERU VS DENMARK 0-1 16-06-2018
ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKẸRIN ARGENTINA VS ICELAND 1-1 16-06-2018
IKẸRIN CROATIA VS NIGERIA 2-0 16-06-2018
Àkọlé àwòrán Croatia gbo ewúro sójú Nàìjíríà

Ìdíje FIFA 2018 ti gbé ojú àwọn agbabọọlu tuntun síta gbàgede.

ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKARUN UN COASTA RICA VS SERBIA 0-1 17-06-2018
IKARUN UN BRAZIL VS SWITZERLAND 1-1 17-06-2018
IKẸFA GERMANY VS MEXICO 0-1 17-06-2018
IKẸFA SWEDEN VS SOUTH KOREA 1-0 18-06-2018
IKEJE BELGIUM VS PANAMA 3-0 18-06-2018
IKEJE TUNISIA VS ENGLAND 1-3 18-06-2018
ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKEJỌ COLOMBIA VS JAPAN 1-2 19-06-2018 (AGOGO KAN)
IKẸJỌ POLAND VS SENEGAL 1-2 19-06-2018 (AGOGO MẸRIN)
Àkọlé àwòrán Mexico ni Odò kékeré ti Germany fojú di, wọn ṣíná fún àwọn Germany to gba ife gbẹyin
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Germany to gba ife ẹyẹ gbẹyin náà kógbá wọlé ni Russia 2018
ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKINI RUSSIA VS EGYPT 3-1 19-06-2018
IKINI URUGUAY VS SAUDI ARABIA 1-0 20-06-2018
IKEJI PORTUGAL VS MOROCCO 1-0 20-06-2018
IKEJI IRAN VS SPAIN 0-1 20-06-2018
IKẸTA DENMARK VS AUSTRALIA 1-1 21-06-2018 (AGOGO KAN)
IKẸTA FRANCE VS PERU 1-0 21-06-2018 (AGOGO MẸRIN)
ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKẸRIN ARGENTINA VS CROATIA 0-3 21-06-2018 (AGOGO MEJE)
IKẸRIN NIGERIA VS ICELAND 2-0 22-06-2018 (AGOGO MẸRIN)
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Mertens náà kò gbẹ́yìn nínú ìdíje tòní bí o se ran Belgium lọ́wọ́ láti jáwe olúbori
ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKARUN UN BRAZIL VS COASTA RICA 2-0 22-06-2018 (AGOGO KAN ỌSAN)
IKARUN UN SERBIA VS SWITZERLAND 1-2 22-06-2018 (AGOGO MEJE ALẸ)
IKẸFA SOUTH KOREA VS MEXICO 1-2 23-06-2018 (AGOGO MẸRIN)
IKẸFA GERMANY VS SWEDEN 2-1 23-06-2018 (AGOGO MEJE)
IKEJE BELGIUM VS TUNISIA 5-2 23-06-2018 (AGOGO KAN)
IKEJE ENGLAND VS PANAMA 6-1 24-06-2018 (AGOGO MEJE)
ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKEJỌ JAPAN VS SENEGAL 2-2 24-06-2018 (AGOGO MẸRIN)
IKẸJỌ POLAND VS COLOMBIA 0-3 24-06-2018 (AGOGO MEJE)
Àkọlé àwòrán Croatia gbo ewúro sójú Argentina ní World Cup 2018

Awọn wo lo kù?

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Gbogbo agbára ni ọrọ bọọlu gba bayii, nilẹ tabi lojú ofurufu

Bọọlu gbígbá ti di, 'A ju ara wa lọ; ìjàkadì kọ́'!

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Gbigba bọọlu sáwọ̀n kọja ààwọ̀ dudu tabi pupa

Ikú to n pa ojúgbà ẹni, òwe nla lo n pa fun ni.

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán 'ọ̀rẹ́ lo yẹ kí a máa ṣe; bóyá wọ́n nà wá tàbí a nà wọ́n'
ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKINI URUGUAY VS RUSSIA 3-0 25-06-2018
IKINI SAUDI ARABIA VS EGYPT 2-1 25-06-2018
IKEJI MOROCCO VS SPAIN 2-2 25-06-2018
IKEJI PORTUGAL VS IRAN 1-1 25-06-2018
IKẸTA AUSTRALIA VS PERU 0-2 26-06-2018
IKẸTA DENMARK VS FRANCE 0-0 26-06-2018
ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKẸRIN ARGENTINA VS NIGERIA 2-1 26-06-2018
IKẸRIN CROATIA VS ICELAND 2-1 26-06-2018
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Iṣẹ agbara, ọgbọ́n ati ìṣirò ni bọọlu gbigba bayii
ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKARUN UN SWITZERLAND VS COASTA RICA 2-2 27-06-2018
IKARUN UN SERBIA VS BRAZIL 0-2 27-06-2018
IKẸFA SOUTH KOREA VS GERMANY 2-0 27-06-2018
IKẸFA MEXICO VS SWEDEN 0-3 27-06-2018
IKEJE PANAMA VS TUNISIA 1-2 28-06-2018
IKEJE ENGLAND VS BELGIUM 0-1 28-06-2018
ÌSÒRÍ ORILẸ-EDE TO KOPA KINI WỌN GBÁ? ỌJỌ WO NI WỌN GBÁ IDIJE WỌN?
IKEJỌ SENEGAL VS COLOMBIA 0-1 28-06-2018
IKẸJỌ JAPAN VS POLAND 0-1 28-06-2018
Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ọmọ to ba ṣiṣẹ́ déédé yẹ kò lasiko ayọ̀ kíkún

Ipele akọkọ ninu idije ife ẹyẹ agbaye Russia 2018 ti pari.

Awọn orilẹ-ede kan to kogba wọle nigba ti awọn to yege n tẹsiwaju ninu ipele Komẹsẹ- o- yọ-danu.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionOnímọ̀ ọrọ̀ ajé: Àfíkún ìsúná táwọn asòfin se b‘ófin mu

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption'Lórí ìgbéyàwó mi, ẹ̀ ṣáà jẹ́ kó wà báyìí'