World Cup 2018: Sweden 1- 0 South Korea

Awọn agbabọọlu lorio papa Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Mertens náà kò gbẹ́yìn nínú ìdíje tòní bí o se ran Belgium lọ́wọ́ láti jáwe olúbori

Nínú ìdíje tó ti wáyé lónìí, èyí ní àwọn agbábọ̀ọ̀lù tó fakọyọ tí ìkọ wọn fi gbégba orokè.

Nínú ìdíje láàrín Sweden àti South Korea, Andreas Granvist, ló gbá bọ́ọ̀lù sáwọn.

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Andreas Granqvist lásìkò tó ń fakọ yọ

Ní ti ìdíje láàrín ikọ̀ àgbábọ́ọ̀lù Belgium àti Panama, ńkan kò rọgbọ fún orílẹ̀-èdè Panama to jẹ́ ìgbà àkọ́kọ́ wọn níyí nínú ìdíje ifé ẹ̀yẹ àgbáyé.

Ẹlẹ́sẹ̀ àyo ikọ̀ Belgium ju bọ́ọ̀lù sawọn Panama nínú ipele àkọ̀kọ́.

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Romelu Lakaku ló jẹ lémèejì fún Belgium

Mertens náà kò gbẹ́yìn nínú ìdíje tòní bí o se ran Belgium lọ́wọ́ láti jáwe olúbori.

Image copyright Empics
Àkọlé àwòrán Mertens náà kò gbẹ́yìn nínú ìdíje tòní bí o se ran Belgium lọ́wọ́ láti jáwe olúbori
Image copyright Empics
Àkọlé àwòrán Lẹ́yìn ìdíje Mertens fìdìnú rẹ̀ han
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption'Lórí ìgbéyàwó mi, ẹ̀ ṣáà jẹ́ kó wà báyìí'

Nínú ìdíjeTunisia àti England, àmi ayo meji sí ẹyọ kan ní ìdíje náà pari si nígba ti ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù England gbọ̀nà èbùrú yọ sí Tunsia ni o ku diẹ kí ìdíje pari

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Harry Kane ló gbá bọ́ọ̀lù sawọn ní fẹrẹ́ ti ìdíje yóò pari