Dókítà Ọrẹ: Abiọla ló ra àwọn asọ àti bàtà ECOMOG

Dókítà Ọrẹ: Abiọla ló ra àwọn asọ àti bàtà ECOMOG

Olóògbé MKO Abiọla ti fara jìyà lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà fún orílẹ̀èdè Nàìjíríà nígbà ayé rẹ̀. Dókítà tó ń tọ́jú Abiọla nígbà náà sọ pé o ní ìdí pàtó tí wọ́n fi pa MKO Abiọla.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: