Ayédèrú Jẹẹsí Nàìjíríà ń tà wàràwàrà lọ́jà
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Jẹẹsí Super Eagles: N5,000, N3000, N2,500...

Àwọn ọmọ Nàìjíríà f'ògún Jẹẹsí Super Eagles gbárí pé àwọn kò paá tì láíláí wọn kò sì ní fi ti ipò wọ́n níní idíje ife ẹ̀yẹ àgbáyé Russia 2018 ṣe.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: