'Alagbalúgbú' jẹ́ ọ̀rọ̀ tí Yorùba fi ń ṣàpèjúwe agbára òkun

'Alagbalúgbú' jẹ́ ọ̀rọ̀ tí Yorùba fi ń ṣàpèjúwe agbára òkun

BBC Yorùbá ní káwọn ènìyàn fàmì sí ọ̀rọ̀ 'alagbalúgbú' (re-re-re-mi-mi).

Àmì ohùn ṣe pataki ninu èdè Yoruba nitori pe àmì ohùn lo maa n ya itumọ ọ̀rọ̀ Yoruba sọtọ.

Agbára àti ìwọ̀n omi òkun ni Yorùba maa n sáàbà lo 'alagbalúgbú' fi ṣapejuwe.

Awọn kan gba ibeere naa nigba ti àwọn miran kò gbáa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: