Ọlatunbọsun Blessing Damilọla: Ẹ dẹkún fífi ẹni tó bá kọ ilà sójú ṣe yẹ̀yẹ́ láwùjọ

Ọlatunbọsun Blessing Damilọla: Ẹ dẹkún fífi ẹni tó bá kọ ilà sójú ṣe yẹ̀yẹ́ láwùjọ

Ojú tí àwọn ọmọ Nàìjíríà fi ń wo ilà kíkọ.

Àwọn míì máa ń pè mí ní nọmba 11

Ọlatunbọsun Blessing Damilọla sọ ìrírí rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ènìyàn nítorí pé ọ̀kọlà ni.

Ẹ̀wẹ̀ lójú òpó Facebook, àwọn ènìyàn fèsì rẹpẹtẹ nípa ìhà tí wọ́n kọ sí ilà kíkọ ní ill Yorùbá.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí:

Bakan naa ni BBC ba Obi Damilola ṣorọ, wọn si ṣalaye idi ti wọn fi kọla fun ọmọ wọn nigba naa.