‘Kò sí ǹkan tó jọ ọ̀nà tuntun fún ọkọ̀ ńlá’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Awakọ̀ Ekó: Kò sí ǹkan tó jọ ọ̀nà tuntun fún ọkọ̀ ńlá

Awọn awakọ ọkọ nla to wa ni ipinlẹ Eko ti sọ wi pe awọn ko gbọ nkankan nipa ọna tuntun fun awọn awakọ, lẹyin ti Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ní àwọn ti yan àwọn ọ̀nà tuntun fún wọn.