Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú ọ̀gá ọlọ́pàá
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

#ENDSARS: àwọn ọ̀daràn yóò ní agbára láti ṣiṣẹ́ ibi púpọ̀

Ṣhogunlẹ ni iṣẹ́ SARS pọ̀ lásìkò yìí kọjá àríwísí

Ọgá ọlọ́pàá Abayomi Shogunle woye pe kosi idi kan gboogi lati ko awọn ọlọpaa kogberegbe SARS kuro nilẹ gẹgẹ bi ọpọ eeyan ti n pariwo.

Ọgá ọlọ́pàá naa to ba ile iṣẹ Iroyin BBC Yoruba sọrọ ni pe awọn ti wọn n sọ pe ki ijọba ko SARS nilẹ ko ni ẹri kankan lati fi idi ẹsun wọn mulẹ.

O fi kun ọrọ rẹ pe ọdaran yoo gbode kan ti ijọba ba ko ọlọpaa SARS nilẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: