Adamu Ciroma, gomina báǹkì àpapọ̀ Nàìjíríà jáde láyé

Adamu Ciroma
Àkọlé àwòrán Ọmọ ọdun mẹrinlelọgọrin ni Adamu Ciroma ki o to ku nilu Abuja

Gomina banki apapọ orilẹede Naijiria nigbakanri, Adamu Ciroma ti jade laye.

Gẹgẹ bi awọn mọlẹbi rẹ ṣe sọ, ileewosan kan nilu Abuja ni o dakẹ si ni sjọbọ lẹyin aisan.

Adamu Ciroma wa lara awọn oludasilẹ ẹgbẹ oṣelu APC, to si tun ti figbakan ri jẹ minisita feto iṣuna ni saa akọkọ aarẹ Oluṣẹgun Ọbasanjọ laarin ọdun 1999 si 2003.

Ọdun mẹrinlelọgọrin ni ki ọlọjọ to de baa.

Image copyright Getty Images
Àkọlé àwòrán Ọmọ ọdun mẹrinlelọgọrin ni Adamu Ciroma ki o to ku nilu Abuja