Àwọn ará Ekiti ti bẹrẹ ayẹwo orúkọ wọn
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ekiti Election: Pọpọ sinsin idibo n lọ lọ́wọ́ lawọn wọ́ọ̀dù

Oni loni n jẹ, ẹni a bẹ lọwẹ lori eto idibo ni ipinlẹ Ekiti

Owuro yii ni won bẹrẹ ayewo orukọ, ki idibo to bẹrẹ ni pẹrẹwu lati yan gomina mii dipo Gomina Ayọdele Fayose

Eto idibo ti bere ni ipinle ekiti pelu bi awọn eniyan se lọ si Wọọdu ati Unit wọn lati dibo yan ẹni ti ọkan wọn fẹ.