FFK: 'Ẹ má ránṣẹ́ ìbánikẹ́dùn sí wa mọ́'
Fẹmi Fani Kayọde to ti jẹ minista fun eto irinna ọkọ̀ ofurufu ni Naijiria nigba kan ri sọrọ lori eto aabo Naijiria bayii ati ọna bayọ.
O bẹnu ẹ̀tẹ́ lu bi Aarẹ Buhari ṣe n fọwọ yẹpẹre mú ọ̀rọ̀ àwọn Fulani darandaran to ti n gbẹbọ lọ́wọ́ tonile-talejo ni Naijiria lasiko yii.
FFK sọrọ lori ọ̀fọ̀ to ṣẹ̀ ni Benue, Adamawa, Taraba, Plateau, Zamfara ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ọlọ́pàá 30,000 ní yóò mójútó ìdìbo Ekiti
- Wo Ọ̀jọ̀gbọ́n Eleka tó ń díje fún ipò gómìnà
- Àwọn ṣajẹ tó gbayì jù láwùjọ
FFK ni 'mo sunmọ Buhari, ṣugbọn ko ṣiṣẹ to yẹ nijọba to ń darí'.
O ni ki Buhari dẹkun fifi ọwọ musulumi ati fulani ni mi mu ọrọ itajẹ silẹ yii mọ.