Ilé tó yẹ kí Abiọla gbé, àwọn wo ló ń gbé níbẹ̀?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ilé MKO Abiọlá di ibùgbé àwọ̀n asínwín

MKO Abiọla ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlá rere fún ara rẹ̀ àti àwọn ọm orílẹ̀èdè Nàìjíríà sùgbọọ́n àwọn àlá kan kò wá sí ìmúṣẹ bíi ti ilé tó níi lọ́kàn láti gbé bí ó bá jáwé olúborí gkgẹ́ bíi Ààrẹ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí

Àwòrán àṣekágbá ìpolongo ìdìbò PDP l'Ékìtì

FFK: Ẹ̀jẹ̀ Fulani ti dàpọ̀ mọ́ ti Yorùbá lára mi