'Ìjọba tó lọ ti yá owó kọjá agbára ìpínlẹ̀'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

#EkitiDecides: Oluṣọla Ẹlẹka sọ ibi tí ìjọbá àná bá Ekiti dé

Olùdijé fún ipò gómìnà lábẹ́ àsìá ẹ́gbẹ́ òṣèlú PDP, Oluṣọla Ẹlẹka sọ nípa bí àwọn ìjọba tó ṣáájú ti ṣe se ètò ìjọba rí àti èyi tí òun yóò ṣe bó bá wọ́le.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àkọlé àwòrán Awọn oludije gomina l‘Ekiti