ìkìlò fún Aarẹ Buhari lórí àdéhùn ètò ọrọ̀ ajé ilẹ̀ Afirika
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ìdókòwò Afrika: Àdéhùn lórí ètò ọrọ̀ ajé yìí le lẹ́yìn

Aarẹ Muhammadu Buhari sọ pe oun yoo bọwọ lu iwe adehun lori ètò ọrọ̀ ajé ilẹ̀ Adulawọ laipẹ, ṣugbọn amofin Adebisi Iyaniwura ti kilọ pe igbesẹ naa le maa bimọ re fun orilẹ-ede Naijiria.

Amofin Iyaniwura sọ pe igbesẹ naa le ṣe okunfa kiṣẹ bọ lọwọ ọpọ ọmọ orilẹ-ede Naijira.

Ṣugbọn o tun fi ojú keji woo pe adehun naa si tun le jẹki ọrọ aje Naijiria gbe pẹẹli si.

O ni irufẹ eso ti adehun yii maa bi niiṣe pẹlu awọn igbesẹ tijọba ba gbe pẹlu adehun naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Amofin Iyaniwura kilọ pe ki Aarẹ Buhari ro ọrọ naa daadaa ki o to fọwọ si.