‘À ń fẹ́ kí Ọlorun yàn fún wa l‘Ékìtì’
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ekiti Election: Ará Èkìtì ń fẹ́ gómìnà tí yòò tù wọ́n lára

BBC Yorùbá jáde wádìí èròńgbà àwọn ará Ekiti lórí ìdìbò to m bọ̀.

Asiko to ki awọn eniyan Ekiti jade dibo yan ẹni ti wọn ro pe yoo ṣe ohun ti wọn fẹ.

Ajọ eleto idibo INEC ti fofin de gbigba kaadi nitori gbendeke asiko ti wọn la kalẹ fun un ti pari

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Bayii, oriṣiiriṣii ọrọ lo ti n jade lẹyin ti àwọn eniyan ti gbọ ipolongo awọn oludije loriṣiirṣii bii Kayode Fayemi (APC), Oluṣola Eleka (PDP) ati Otuna Segun Adewale (ADP).

Ọjọ́ Abamẹta ni eto idibo ọhun yoo waye.