Ìdìbò Ekiti lọ́ geerege
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

U.S: Ètò ìdìbò Ekiti gbọnjẹ fẹ́gbẹ́ gbàwò bọ

Asojú ilẹ̀ Amẹ́ríka John Bray tó péjú sí ibi ìdìbo Ekiti bá akọ̀rọ̀yìn BBC sọ̀rọ̀ lórí ètò ìdìbo tó wáyé nípìnlẹ̀ Ekiti.