Èdè Ekiti ni wọ́n fi kí Fayẹmi kú oríire
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Àwọn obìnrin Ekiti fi tọ̀yàyà tọ̀yàyà kí Fayẹmi

Láti ìgbà tí èsì ìdìbò ìpínlẹ̀ Ekiti ti jáde ní ọjọ́ àìkú, àwọn ará ìpínlẹ̀ náà ti bẹ̀rẹ̀ àjọyọ̀ fún àṣeyọrí Kayode Fayemi.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: