'Oníbárà ló pọ̀ jù nínú àwọn òṣèrè'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Yẹmi Ṣolade: Ó ṣe ni láànú pé oníbárà ló pọ̀ jù láàrin wa

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àtẹ̀jáde àti ìfohùnsíta ló ti ń jẹyọ lórí ẹ̀rọ̀ ayélujára nípa bí àwọn òṣèré ṣe ń polongo ọrọ̀ wọn.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: