Olubọyọ: Babalawo pe Adeyẹmi pé òògùn rẹ̀ kò jẹ́

Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ kan tí wọ́n ti ń wá Khadijat tó jẹ́ ọmọ igbákeji gómínà tẹ́lẹ̀rí ní ìpínlẹ̀ Ondo ni wọ́n bá òkú rẹ̀ ní ilé àfẹ́sọ́nà rẹ̀, Adeyemi Alao.

Alukoro fun ile iṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo to ba BBC Yoruba sọrọ wi pe ṣe ni o gbe oku Khadijat sinu ile fun ọjọ mẹfa nitori ifurasi.

Ṣugbọn o fidi rẹ mulẹ pe awọn ọlọpaa yoo duro de ayẹwo awọn dokita ki awọn to le sọ pato ohun to ṣẹlẹ.

Ẹwẹ, baba rẹ Alhaji Lasisi Oluboyo gbagbọ pe Khadijat kii ṣe ọmọ onirinkurin.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí: