Katsina-Alu: Adájọ́ àgbà Nàíjíríà ni, nígbà ayé rẹ̀

Aloysious Katsina-Alu Image copyright Nigeria Supreme Court

Adájọ́ àgbà tẹ́lẹ̀ rí lórílẹ̀èdè Nàìjíríà, Aloysious Katsina-Alu ti jáde láyé.

Ìròyìn tó tó ilé iṣẹ́ BBC létí láti ọ̀dọ̀ mọ̀lẹ́bí olóògbé kan jẹ́ kó di mímọ̀ pé, óòtọ̀ ni pé ó ti jáde láyé lówùrọ̀ òní.

Olóògbé náà jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ushongo ní ìpínlẹ̀ Benue, ó sì jẹ́ adájọ́ àgbà láàrin ọgbọ̀njọ́ oṣù kejìlá, ọdún 2009 sí ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2011.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ sí:

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionBaba Khadijat Oluboyo jẹ́rìí ọmọ rẹ̀

Related Topics