Ọlọpaa lu ẹnu ọna ile Saraki pa
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Saraki: Ọlọ́pàá dí ẹnu ọ̀nà ilé Ààrẹ ilé aṣòfin àgbà

Awọn ọlọpaa ti di énu ọna ile aarẹ ile asofin agba l'Abuja Bukola Saraki ati igbakeji rẹ Ike Ekweremadu pa.

A gbọ pe awọn ọlọpaa naa de iwaju ile Saraki ni idaji ọjọ Iṣẹgun.

Ẹwẹ, awọn ọ́ga ọlọpaa orilẹede naijiria Ibrahim Idris ti ke pe Saraki tẹlẹ lati yọju si ile iṣẹ ọlọpaa fun ifọrọwanilẹnuwo lori ibaṣepọ rẹ pẹlu awọn adigunjale to ṣọsẹ nilu Offa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: