Ṣé agbégbé ilẹ Afirika tó ní àṣeyọrí jùlọ nì yí?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ìlu Tanzania ni Bernard Kiwia tí ń ṣe móríyá fún àwùjọ rẹ

Ilé ìwé aláṣeyọrí Twende ní orílẹèdè Tanzania ni Bernard Kiwia tí ó ń ṣe móríyá fún àwùjọ rẹ láti wá ojútùú sí àwọn ìsòro tó ń dojó kọwọn lábẹlé.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

BBCINNOVATORS