Ipa tí rìbá gbígbà yóò ní lórí ikọ̀ agbábọ́ọ́lù Nàíjíríà
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Adegboye Onigbinde àti Felix Owolabi: Ó yẹ kí Nàíjíríà tọ́jú àwọn olùkọ́ni léré bọ́ọ́lù rẹ

BBC Yoruba fọrọ wa awọn àgbà ọ̀jẹ̀ méjì lẹ́ka eré bọ́ọ́lù lẹnu wo lori fidio kan ti Ileesẹ BBC gbe jade pẹ̀lú oluwadi ọtẹlẹmuyẹ kan, Anas, eyi to n sọ bi olukọni lere bọọlu fẹgbẹ agbabọọlu agba ilẹ Naijiria, Salisu Yusuff se gba ẹgbẹrun kan dọla gẹgẹ bii owo abẹtẹlẹ lati ko agba bọọlu meji lọ fun idije ife ẹyẹ laarin awọn orilẹ-ede nilẹ Adulawọ (CHAN).

Awọn mejeeji si sọ̀ nipa ipa ti iru igbesẹ yii lee ni lori ẹka ere bọọlu nilẹ wa ti iwadi naa ba fi jẹ otitọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: