Aṣẹ́wó olóṣèlú ni àwọn sẹ́nẹ́tọ̀ tí wọ́n fi APC sílẹ̀
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

APC àti PDP: 'Aṣẹ́wó olóṣèlú l'àwọn sẹ́nẹ́tọ̀ tó ya lọ

Sẹ́nẹ́tọ̀ Tayo Alasoadura ti sọ pe aṣẹwo oloṣelu ni awọn mẹẹdogun ọmọ ile igbimọ asofin agba l'Abuja ti wọn fi ẹgbẹ ọṣelu APC silẹ lọ si PDP.

Nigbati o n ba BBC Yoruba sọrọ, sẹ́nẹ́tọ̀ Alasoadura fidi rẹ mulẹ pe igbesẹ awọn asofin fihan pe wọn o mọ nkan ti wọn n ṣe lati ibẹrẹ wa.

O ni wọn kan wọ inu oṣelu nitori ohun ti wọn le ri nibẹ ni.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: