ọdún mẹ́wàá ni passport Nàìjírìa dà báyìí
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Passport Nàìjírìa: Gbèdéke ọdún mẹ́wàá ti wà fún páálí ìrìnnà Nàìjírìa

Idunnun ṣubu layọ fun awọn ọmọ Naijiria bi ijọba apapọ ti sọ iwe irinna di ọdun mẹwaa lati ọdun marun un ti o wa tẹlẹ ki o to di pipaarọ.

Awọn eeyan to ba BBC Yoruba sọrọ ni ofisi iwe irinna ni Ikoyi nipinlẹ Eko kan saara si igbẹsẹ ijọba naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: