Ǹjẹ́ o mọ ìdí ti n kò ṣe dìbò gómìnà ìpínlẹ́ Ekiti?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Fẹla Durotoye: ọ̀rọ̀ ìṣọ̀kan Nàìjíríà tó àpérò ọmọ eríwo

Ọ̀rọ̀ ṣe pàtàki nínu ètò ìṣẹ̀dá láyé, Fẹla Durotoye ba BBC Yorùbá sọ̀rọ̀ lórí ìdìbò Ekiti tó kọjá.

Olùdíje kan fún ipò aarẹ Naijiria lọdun 2019, Fẹla Durotoye, to jẹ ọmọ bibi ipinlẹ Ekiti ki oríkì agbára ọ̀rọ̀ pé....

"Ọ̀rọ̀ ṣe kókó nilé ayé

Ọ̀rọ̀ la fi ń pín ìlú

Ọ̀rọ̀ la fi ń kó ìlú jọ

Ọ̀rọ̀ la fi ń bẹ̀rẹ̀ ogun

Ọ̀rọ̀ la fi ń parí ogun

Ẹni ti yoo darí Nàìjíríà ni 2019 gbọ́dọ̀ lè sọ̀rọ̀ alaafia fún ìṣọkan Nàìjíríà".

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí