Fatimah: Kò sí ẹni ti kò le yi agbègbè rẹ padà
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ìgbésí ayé àwọn ọmọdébìnrin wọ̀nyìí di ọ̀tun láti 2008

Oriṣii idanilẹkọọ ló n fun awọn èwe yii lasiko eré bọọlu

Fatimah Abdulkadir Adan n fi ẹkọ nipa ere bọọlu gbigba tun igbesi aye awọn ọmọbinrin agbegbe rẹ ṣe.

BBC Innovations pẹ̀lu ajọṣepọ ilé iṣẹ arannilọwọ ti kii ṣe tijọba, iyẹn, Bill and Melinda Gates Foundation.