Ìjọba kò lẹ́bi lórí ọ̀rọ̀ ìkọlù ilé ìwòsàn àwọn alárùn ọpọlọ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ilé ìwòsàn: ẹ má bú ijọba lórí ìkọlù alárùn ọpọlọ

Akòwé àgbà fún ìgbìmọ̀ ìlé ìwòsàn ní ìpínlẹ̀ Ondo Dr Niran Ikumọla ti bu ẹnu atẹ lu bi awọn ẹgbẹ awọn nọọsi nipinlẹ Ondo ti ṣe 'wọde lẹyin ti alarun ọpọlọ kan lu nọọsi ati dokita to n tọju rẹ nilu Akure.

Nigba ti o ba BBC Yoruba sọrọ, Ikumọla rọ awọn nọọsi lati ba ijọba sọ ohunkohun ti o ba n dun wọn ni itubi-inubi.

O fi kun ọrọ rẹ pe ijọba n gbiyanju lati pese awọn nkan ti wọn nilo lati ṣe iṣẹ wọn laisi ipalara.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: