Àwọn àwòrán tó gbayì láti Ojúdé Ọba

Ẹ fójú lóúnjẹ níbi ayẹyẹ Ojúdé Ọba ti ọdún 2018 tó ńwáyé lọ́wọ́lọ́wọ́ ní Ijẹbu Ode

Ojúdé Ọba
Àkọlé àwòrán,

Ẹlẹ́gbẹ́ ń jẹgbẹ́ gbé àṣà Yorùbá ga pẹ̀lú aṣọ wọn

Àkọlé àwòrán,

Ẹlẹ́gbẹ́ ń jẹgbẹ́ gbé àṣà Yorùbá ga pẹ̀lú aṣọ wọn

Àkọlé àwòrán,

Ojúdé Ọba 2018: Asọ ń pe asọ ránsẹ́

Àkọlé àwòrán,

Ibi ìgbàlejò ìtagbangba fún Ojúde Ọba

Àkọlé àwòrán,

Olóyè ilẹ̀ Ijẹbu lórí ẹṣin

Àkọlé àwòrán,

Àwọn aṣọ ìbílẹ̀ ń ṣẹ́yọ lẹ́lẹ́gbẹ́ ńjẹgbẹ́

Àkọlé àwòrán,

Awùjalẹ̀ ti ìlú Ijẹbu, Ọba Sikiru Adetọna níbi ayẹyẹ Ojúde Ọba

Àkọlé àwòrán,

Ẹgbẹ́ t'ọba làṣẹ Akilẹ-Ijẹbu

Àkọlé àwòrán,

Àwọn Sẹ́nétọ̀ Nàìjíríà kò gbẹ́yìn níbi ayẹyẹ Ojúdé Ọba

Àkọlé àwòrán,

Gígun ẹṣin náà kò gbẹ́yìn lára ètò fún ayẹyẹ Ojúdé Ọba

Àkọlé àwòrán,

Ẹlẹ́gbẹ́ ń jẹgbẹ́ gbé àṣà Yorùbá ga pẹ̀lú aṣọ wọn

Àkọlé àwòrán,

Olóyè Balogun Alatishe ti ilẹ̀ Ijẹbu yan kiri lórí ẹṣin

Àkọlé àwòrán,

Ọ̀túnba Túnwàṣe tó tún jẹ́ alákoso ilé ifowópamọ́ FCMB àti ìyàwó rẹ̀

Àkọlé àwòrán,

Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin, Bukola Saraki dé síbí ayẹyẹ náà

Àkọlé àwòrán,

Sẹ́nétọ̀ Dino Melaye náà wà níkàlẹ̀

Àkọlé àwòrán,

Ìwọ́de ìdílé Kuku ní Ojúdé Ọba

Àkọlé àwòrán,

Egbẹ́ Bobagbinmo obìnrin Akile ijebu lọ kí Oba Awujale kú ìkàlẹ̀