Ìbẹ̀rẹ̀ ogun ni à ń rí kò sẹni tó máa ń mọ àdánù rẹ̀ tán
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọdún kan lẹ́yìn ogun Musulumi Rohingya, ìbànújẹ̀ dorí àgbà kodò

Ìgbé ayé àwọn aṣàtìpó Rohingya kò rọrùn rárá.

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ aṣàtìpó to sá kuro torí ogun Rohingya lo ṣì ń gbé nínú ìbànújẹ́ àti ẹ̀rù báyìí tó jẹ́ ọdún kan lẹyin iṣẹlẹ naa.

Ọmọ ọdun mẹẹdogun yii sọ ohun ti oju rẹ n ri pẹlu ẹ̀rù to n baa lori oyun to ni fun baba arúgbó to fẹ ẹ nibudo aṣatipo.