'Wọ́n r[pé mo ya wèrè ni Saudi lẹ́yìn ikú ọkọ mi'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Kádàrá ní ọ̀rọ̀ ẹ̀dá láyé, Mo gbà pé Ọlọrun ló kọ ikú ọkọ mi ni Saudi

Mo gba pé a dá mi sí láti tọ́jú àwọn ọmọ wa mẹta ti ọkọ mi fi sílẹ̀ lọ ni

Abilekọ Yetunde Morenikeji Raji to jẹ aya oloogbe Ajani Raji ba BBC Yorùbá sọrọ lori iṣẹlẹ to gba ẹ̀mí ọkọ rẹ to tun sọ oun di aláàbọ̀ ara.

O mẹnuba bi ọna iṣẹ naa ṣe ṣi silẹ fun ọkọ rẹ ni Saudi lẹyin to ṣiṣe pelu UCH àti fasiti LAUTECH

Yetunde Raji sọ nipa bi wọn ṣe kàgbákò ni ó ku ọ̀la ti oun a pada si orilẹ-ede Naijiria.