Olúwó: Èmi ni Awùjalẹ̀, Aláke, Ọba Eko fún gbogbo ọmọ Ìwó

Olúwó: Èmi ni Awùjalẹ̀, Aláke, Ọba Eko fún gbogbo ọmọ Ìwó

Olúwo ti ilú Iwo, Ọba Abdulrasheed Akanbi, Telu 1 ló jẹ́ Ọba ìlú Ìwó ìkẹrìndínlógún tí yóò jẹ.

Ọba Abdulrasheed Adewale Akanbi ni òun ni aṣojú elédùmarè nílé ayé àti pé òun ní àṣẹ lórí òrìṣa.

Ó ṣe àpèjúwe ọba gẹ́gẹ́ bí ọlọ́run, ó ní ọba kìí ṣe ènìyàn nítorí náà, ọba kìí ṣe aláṣẹ èkejì òrìṣà gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe máà ń sọ ọ́.

Ọba Adewale sọ wí pe ibi kíbi tí ọba bá wà, bàbá gbogbo wọn lòun jẹ́ nítorí wí pé òun ni bàbá Yorùbá.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: