Báwo lẹ ṣe gbọ́ èdè Yorùba sí?

Báwo lẹ ṣe gbọ́ èdè Yorùba sí?

Pé a jẹ́ ọmọ Yorùbá kọjáa kí á kàn máa jk orúkọ Yorùbá níkan. Mímọ̀, gbígbọ́, sísọ àti kíkọ èdè ẹni sílẹ̀ ṣe pàtàkì.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: