A gbọ́ ti ẹran ejò, se ẹ ti mu ọtí wáìnì ejò rí?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Mimu ẹ̀jẹ̀ ejò máa ń fún ọkùnrin lágbára

Àwọn tó ti jingíri nínú ẹran ejò jíjẹ ní ẹni tó ti ju àádọ́ta ọdún lọ ló leè mu ọtí wáìnì tí wọ́n ń ṣe látara ẹran ejò.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: