'Láti ọmọ̀ oṣù mẹ́ta ló ti gbọ́ ìlù'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Bàbá Àyàn: Láti ọmọ̀ oṣù mẹ́ta ló ti gbọ́ ìlù

Ọmọ ọdún mọ́kànlá ni Oluwapamilẹrin Michael Ayanlere tó ń fi ìlù dárà tó tún ń gba àwọn òbí níyànjú.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

PDP pè fún fífi Kemi Adeosun jófin

APC àti PDP takora wọn lórí Olùsirò owó àgba Ọsun tó fisẹ́ sílẹ̀

Njẹ́ o mọ̀ pé ẹ̀yà Yorúbá nìkan kọ́ ló ń ta ayò ọlọ́pọ́n?