Èrò àwọn oníbàárà Skye Bank tó porúkọ dà
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Polaris Bank Nigeria: Ẹ̀rù ń bà wá o - Oníbàárà

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ní òmìmì kan ò mi àwọn lórí owó wọn tó wà ní ìpamọ́ Polaris Bank bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn kan ti lọ kó gbogbo owó wọn kúrò nítorí àyípada tó bá ilé ìfowopamọ́ náà.