Iṣẹ́ abẹ láti ya ìbejì tó lẹ̀pọ̀ yọrí sí rere l'Abuja

Ìbejì Image copyright Dogara media office
Àkọlé àwòrán Àwọn ìbejì tí wan yà sọ́tọ̀

Awọn dokita kan ṣe iṣẹ abẹ lati ya awọn ibeji ti wọn lẹpọ ni ile iwosan ikọni Fasiti Ilu Abuja to wa ni Gwagwalada lọjọ Iṣẹgun.

Olori awọn dokita ọun Nuhu Kwajafa lo kede aṣeyọri iṣẹ abẹ naa loju opo Instagram rẹ.

Dokita Kwajafa sọ pe isẹ awọn ni igbiyanju lati doola ẹmi gẹgẹ oniṣegun, ati wipe o ṣe pataki fun awọn lati fifẹ han si awọn eniyan.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media caption67 year old mother: Mo kojú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àìsàn fún ọdún 35 lẹ̀yín ìgbéyàwò
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionAdetoun Ogunṣẹyẹ: ìrìnàjò ẹ̀kọ́ mi títí dé òkè kò rọrùn rárá

'Àwa kò lè san ju #22,500 lọ fún Minimum wage'

O fi kun ọrọ rẹ pe aye yii yoo dara ju bayiii lọ ti onikaluku ba n fifẹ han si ọmọlakeju wọn.

Image copyright Dogara media office
Àkọlé àwòrán Àwọn ìbejì tí wan yà sọ́tọ̀

Iroyin to tẹ wa lọwọ sọ pe miliọnu naira ni owo ti wọn san fun iṣẹ abẹ lati ya awọn ọmọ naa.