'A jọ wà nínú ọkọ̀ kan náà ni kó tó bọ́ọ́'lẹ̀'
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Alábaṣiṣẹ́ ọkùnrin tó kú sínú odò Ọ̀sà sọ bó ṣe rí

Nígbà tí BBC Yorùbá kàn sí àjọ tó ń rí sí ìṣẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì ní ìpínlẹ̀ Eko (LASEMA), agbẹnusọ àjọ náà, Kehinde Adebayọ jẹ́ kó di mímọ̀ pé àwọn òṣìṣẹ́ adóòlà gbìyànjú láti yọ ọ́ jáde láàyè.

Ṣùgbọ́n pẹ̀lú gbogbo ìgbìyànjú wọn, arákùnrin náà rékọjá sí ọ̀run alákeji.