Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé àlákálàá lè jẹ́ àfihàn ààrùn ọpọlọ?

Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé àlákálàá lè jẹ́ àfihàn ààrùn ọpọlọ?

Bí ìjọba àpapọ̀ ṣe fi ọ̀rọ̀ síta wí pé ìdá ọgbọ̀n nínú ọgọ́rùn-un ọmọ Naijiria ló ní ààrùn ọpọlọ, àwọn onímọ̀ ní ọ̀rọ̀ yìí kìí ṣe irọ́ rárá.

Ọ̀kan nínú àwọn onímọ̀ náà ni Ọ̀jọ̀gbọ́n Adeoye Oyewole tó ṣàlàyé fún BBC àwọn oun tí ènìyàn ní láti kọbi ara sí tó lè ṣe àfìhàn pé àsìkò ti tó fún àyẹ̀wò àwọn dókítà tó ń mójú tó ọpọlọ.

Púpọ̀ nínú àwọn oun tí ọ̀jọ̀gbọ́n Oyewole sọ ya'ni lẹ́nu púpọ̀.

Ní ṣókí, àwọn àlàyé ọ̀rọ̀ náà rèé:

Àwọn ìròyìn mìíràn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: