ASUU strike: 'Màá gba bílíọ̀nù mẹ́wàá tí wọ́n bá tún dími lọ́wọ́ iṣẹ́'

ASUU strike: 'Màá gba bílíọ̀nù mẹ́wàá tí wọ́n bá tún dími lọ́wọ́ iṣẹ́'

Ajeje ọwọ kan ko gbẹru dori, agbajọ ọwọ ni aa fi sọya ni Yoruba maa n wi. Ṣugbọn bi ti Ọjọgbọ Sunday Edeko olukọni ni fasiti Ambrose Ali nipinlẹ Edo kọ, lẹyin to kilọ fun ajọ ASUU pe oun ko fọwọ si iyanṣelodi ti wọn gunle.

Ọjọgbọn Edeko ni ajọ ASUU ko lẹtọ labẹ ofin lati di oun lọwọ nibi ti oun ba ti n kọ awọn akẹẹkọ, nitori oun kii ṣe ọmọ ẹgbẹ ajọ naa.

O kilọ pe oun yoo gba biliọnu mẹwaa owo naira ti ajọ naa tun di oun lọwọ iṣẹ.