''Ikọ̀ Super Falcons ṣẹ́ṣẹ́ ń mẹ́yẹ bọ̀ lápò nio''
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

AWCON: Ikọ̀ Super Falcons ṣetán láti kojú Equatorial Guinea

Ikọ̀ Super Falcons ṣẹ́ṣẹ́ ń mẹ́yẹ bọ̀ lápò nio ninu idije AWCON,'' Ẹlẹ́sẹ̀ ayò Francisca Ordega fun ẹgbẹ agbabọọlu obinrin Naijiria lo sọ bẹẹ.

Ordega to wa lara awọn agbabọọlu to gbayo wọle ninu ifẹsẹwọnsẹ Naijria ati Zambia ní àwọn ṣetán láti kojú Equatorial Guinea lẹ́yìn tí wọ́n na Zambia lálù bolẹ̀.

Ẹ o ranti pe Naijiria fidir.emi pẹlu ayo kan sodo ninu ifẹsẹwọnsẹ akọkọ ti wọn gba ninu idije AWCON to n lọ lọwọ lorilẹede Ghana.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: