Chef Adefunkẹ: Òórùn ewé tí wọ́n n pọ́n ìrẹsì ọ̀fadà si jẹ́ adùn lọ́tọ̀

Chef Adefunkẹ: Òórùn ewé tí wọ́n n pọ́n ìrẹsì ọ̀fadà si jẹ́ adùn lọ́tọ̀

Ọlọwọ ṣibi Adefunke Temitọpẹ Olutuyi lo se ounjẹ àdidun ọsẹ yii lórí ajẹpọnnula.

Irẹsi ọfada jẹ ọkan lara awọn ounjẹ aṣara loore to n fun ni lokun ati agbara.

Lara awọn eroja ti wọn fi n se ọbẹ ọfada ni: ata rodo, epo pupa, ẹja yiyan, alubọsa, pọnmọ, inu ẹran bii ṣaki, ẹdọ, abọdi, iru, iyọ, ede lilọ àti bẹẹ bẹẹ lọ.

Oriṣi ounjẹ lawon Yoruba fẹran ṣugbọn imọtoto lasiko ti eeyan ba n se e lo ṣe pataki julọ.