Wòlíì Àrólé: Wí tẹ̀lé mi...

Wòlíì Àrólé: Wí tẹ̀lé mi...

Gbajúgbajà apanilẹ́rin ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà, Oluwatoyin Bayegun tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Wòlíì Àrólé dẹ́rìín pẹ̀kẹ̀ẹ́ àwọn òyìnbó aláwọ̀funfun tó jẹ́ òṣìṣẹ́ ilé iṣẹ́ ìròyìn BBC tó wà ní ìlú London.