Ijó Bàtá ti Yorùbá gb'oríyìn ní Calabar Festival 2018

Ijó Bàtá ti Yorùbá gb'oríyìn ní Calabar Festival 2018

Oṣù Kejìlá ọdọọdún ni ayẹyẹ Calabar Carnival ma n wáyé ní ìpínlẹ̀ Cross River fún ìgbélárugẹ́ àṣà àti iṣe orílẹ̀èdè Nàìjíríà.